Asa [FI] - Iba lyrics

Published

0 111 0

Asa [FI] - Iba lyrics

Everyday, so God... Bacause of you. I dey live, I dey breath, I dey eat So, I wanna have some talk with you Orun, silekun I wanna have some talk, [with] you o (2xe) Nitori re mose n lola Nitori re mose n s'oge Nitori re mose n ra moto Mowole, M'oboluwa mi soro Nitori re mose wa laye Nitori re mose n woso sara Nitori re moji l'owuro Mow'aye mi lode ye A o, Aa a o o ibafeledu'a A o, Aa a o o Mowole, M'obolowa mi soro Nitori re mose n gbo iroyin ayo Lais'owo laisi nkankan Iya oni, layoola o B'oluwa tiwi, be naa lori Jiji moji lowuro Moji si inu ipese re Ayo at'alafia ye ye O, o o oni pe ki n ma se beru A o, Aa a o o ibafeledu'a A o, Aa a o o Mowole, M'obolowa mi soro Melo la fe so Melo lo si n bowa Melo la fe so, eh Melo lo si n bowa Nitori re mose n sa ko, everyday, eh eh Nitori re mojijo lese mi, oh oh oh, oh oh Ninu iponju, Ninu idamu B'ebi ba n p'ona Mawole, maboluwa mi soro B'emi o le yan Baye ba foju dimi B'emi o le ni Mawole, maboluwa mi soro A o, Aa a o o ibafeledu'a A o, Aa a o o Mowole, M'obolowa mi soro Ninu iponju, Ninu idamu B'ebi ba n p'ona Mawole, maboluwa mi soro Mioni foju sunkun mo o Aye loja, oh oh... Orun... Orunile And that's fine by me... Eh eh... Oh... Ye ye... Bring it down... Oh oh...