Angelique Kidjo - Bahia lyrics

Published

0 221 0

Angelique Kidjo - Bahia lyrics

Aburo, orè ni gbogbowa, ewa ka lolé Aburo, ibi kan ni wao, kamura si ifè Ouidah ni ilé ti bahia Ti émin mon wa, ri yin lénin o Bahia, bahia, bahia, bahia, bahia, bahia Ilé ti babawa djinan, awa fè lolé Bahia ilou ti awa lenin, okpè gan si ilé Ogun ti awon agbalagba, shé kalè foun wa o Logbé wa lo si bahia, gbé gbogbowa kpo Bahia, bahia, bahia, bahia, bahia, bahia Odjo ikadé wa m'bowa o, ti ale rira wa Ewa ka moura foun odjo yin, ninou oyaya Oluwa foun wa ni ayé, edjè ka du kpè Bahia kpa gbogbowa kpo, iréti wa lonan Aburo, orè ni gbogbowa, ewa ka lolé Aburo, ibi kan ni wao, kamura si ifè Ouidah ni ilé ti bahia Ti émin mon wa, ri yin lénin o Oré ifé ayé ilé, oré ifé ayé ilé... Aburo, orè ni gbogbowa, ewa ka lolé Aburo, ibi kan ni wao, kamura si ifè Ouidah ni ilé ti bahia Ti émin mon wa, ri yin lénin o Oré ifé ayé ilé, oré ifé ayé ilé... ---------------------------------------------------------------- TRANSLATION: Bahia is so far from Motherland But the spirit is still alive One day we'll come together I want to cross that bridge It leads from Ouidah to Bahia